QRfiNMLA!
QRfiNMLA!
First First
Printe Pr inted d
1908. 1908.
Second Sec ond
Print Pr int
1972.
Pri P rint nted ed OMOLAYO
by:-
S T A N D A R D P R ES ES S O F Akure Road, P. O. Box 3, ADO-EKITI.
NIGERIA
Alufa, Lijadu iiiiiu Igbo-lfa.
IFIJUBfi,
Al u pa T o m H a r d i n g — Oyinb o onis^ Olorun ti o se Qga-lwe fun awpn Akpko Ise Olprun ni Ile-I^kp Giga ti ('.M.S. li fik'6 la ti pdun 1884 de 1887,—A labo juto Isp Olprun I’Abpok u ta lati pdun 1888 de 1895,—I r ij u ati Akpwe fu n C.M.S. lati pdun 1896 de 1902,— Alabojuto Isp Olpru n 1’ Ib adan lati pdiin 1892 ti ti di pni ati nipa an u Olprun, Iwp ti o kii li iilipba lar in awpn Oyinbo onisp Olp ran ni gbogbo Iwp-o run Afi'ika, Iwp ni mo fi Iwe kekere mi yi juba loni.
Nigbati ise da awa mejeeji p6 ninu Ile-Eko Giga ti C.M.S. li Eko lati pdun 1885 de 1890, Iwo bi oga-ise naa ati emi bi alagbase, Qlorun gbin igi-ore kan saarin wa; O fi i fun awa mejeeji lati maa roko-si, On paa paa si nrojo ibukiin re le e lori. Mo dupe lowo Olpruri pe igi-ore naa ti On gbin saarin wa ti hu, o gbile, o si bcresi iso eso nisisiyi. MO FI IWE YI JUBA R E ni iranti aniyan re igbanaa pe a ba le ri owp awon I we Kika li ede Yoruba lati maa se bi iranw o fun awon Akeko Ise Qloru n ni lie Yoruba si ati-mo iwa ati ise awon enia ile wa daju, fun ilo won bi Oniwasu iebin pla. Ati nigbati o di mimo fun o pe mo ngbidanwo ati-se akojo iru awon iwe bawpnyi, ppp iranwo li o ti se fun mi nip a prp iyanjii ati inawo re fun mi si pna naa. Ipase tire kan naa ni awpn Oyinbo miran bi awpn Oloogbe Alufaa J.W. Dickenson ati J. Brayne ati Yeba Marion Goodall tele nipa inurere wpn si pna yi, —awpn eniti o ti goke odo Jordani si ibi isimi wpn. Ki Olp run masai fi wpn si ipo rere Ipwp ptiin Re Iphun. Ninu awpn ore to otp ti mbe laaye sibe ti ko si ye ki ng gbagbe nihin ni Olpla obirin ti Arkidiakoni Melville Jones fun iyanju re igbagbogbo ti 6 dabi tire si mi ati si ohun rere gbogbo ti o je ti pmp ibile Yoruba. MO TUN JUBA NYIN O,— nitori enyin ko korira ‘Sekooni’ ninu enikeni laarin He enia dudu; kaka bee enyin nfi tpka ntp kan nyin kp-ni pe ‘Aba-enu-lasan’ ko le so oh un rere ti a nfe di t ’eni. "* MO TUN JUBA NYIN O, — nitori enyin ko wipe ki eniti 6 ri-je- mase je, enyin ko wipe ki alairi-je f’ebi sun, enyin ko wipe ki eniti otutu npa mase yana, enyin ko wipe ki eniti ooru nmu mase sun oyi, beeni e ko si wipe ki ol’igi eeji mase np’se sin a# Ki Qlprun biikun ise nyin laarin wa, ki O si fi ppplppp eso itunu ke nyin latinu re wa. Amin. Iwe mi kekere yi je kikini ninu eso na a; §ugbpn adura pkan mi ni pe ki 6 le je agbara nla Ipwp awpn iranse Jesu Kristi ni ile Yoruba, ati ki 6 si le ft bee di iwe - ayple kan fun gbogbo enia Emi ni Ore re nitooto E. M. LIJAEiU Gbangan Ajihinrere-lpfe Ode Ondo, July 7, 1907.
SI AWON OLUFE IFE ILE IBI WON Enyin Olufe, Bi ojo se ng gori ojo, ti ose ng yi lu ose, ti igba si ng tele ra won: be e I’pclun ori iwe yi ng di pupo'to be e ti a ko ba ri eni-bi-eni enia-bi-enia fowosowopo se atunse ati atu nte iwe na ki nw pn siran as’odefun ifihanatikikagb ogb oenia yio di igbagbe larin wa, iranti ki yio si si fun un mo Toril? ede wa yi i. Pe Olorun gbe awon ‘olufe ile ibi won’ dide ni sa a yi, ti nwon si nfi t’gkan t’ara ng fe ki asa ati itan ile ibi won wa ni pipe sansan je oh un ayp ati iwuri fun mi. Awpn sa a li o rp mi lati ypda atunte awpn iwe mefa ti baba mi agba Ologbe Alufa E. M. Lijadu §e: a .n .:- (1) Aribiloso (2) Ifa (3) Ode Gaga Ara Ilujugbe (4). Gram ma Yoru ba (5). Orunm la ati (6). Sobo-Aro-bi Odu Apa I & II ati awpn iwe miran ti koi ti fi oju kan erp itewe. Nigbati ohu n wa si ti §pkan lori eto yi, a da egbe kan sile ti a pe ni ‘Egbe Oludabobo A sa Yoruba.’ I§e egbe yi ni lati ma a ran enikeni ti o ba ni ife asa ile Y orub a Ipwp. Egbe na a yio ma se iranlpwp fun tite iwe ti o ba niye lori ti yio si se ile wa yi ni rere, bakanna a ni yio ma sa gbogbo agbara re Ipnakpna lati ri pe awpn ohun abpba ile wa ti o spwpn ko po o ra mp wa loju bikosepe a lo wpn fun ire, ogo ati igbekele orile-ede wa. Nito ri idi eyi..................... Mo jub a Olprun Eleda, Eniti o fi apak an pgbpn re ta w^ Ipre. Mo si dupe gidigidi Ipwp awpn enia wpnyi - ti wpn ba mi pile egbe yi ti wpn si se akojp owo fu n atunse ati atu nte awpn iwe na a. e . n . O l o y e S. A. Fawehinmi, (2). lyaafin Fp la Fasida. (3). Qgbeni Dptu n Odunuga. Ibere li eyi, a ni igbagbp wipe e o tewp gba awpn iwe na bi wpn ba se njade li pkppkan gege bi awpn baba wa se gba wpn tayptayp nisa-aju. Mo si ni ireti pe lehin eyi, e o gbiyanju lati darap p mp wa ninu Egbe Oludabo bo A§a Yo ruba. Mo ki yin o eniyin ara: Mo juba yin o enyin agba, ki Qlpru n ma fi eyi se asemp fun wa o. Aje. Ajihinrerelpfe House, 64, Lokun Street, P. O. Box 76, Teleph one 85, Ode-O ndo.
Emi ni Tiyin Nitotp, Enipwp E. A. LIJA DU , Onipo risan Keta Alufa Ajihinrerelpfe, Ondo. 10 : 12 : 71.
iv^^E n. ORUNMLA Bi a o soro Oriin mla li asojale, a ko le saispro ohim m eta wonyi si i — Eki'ni, ohun Iwa-Olorun tf awon babaiila wa pin fa n u: ekeji, ohun Iwa-enia ti nwon fifun u peiu: eketa, awon ekoyeko ti o ti enu re jade. Ekini ni nik an li a o dawole iiisisiyi ninu iwe yi; a o fi meji iyoku sile digbose. Nwonyi li oold Orunmla ti a fi se ipile asa ro wa ninu iwe yi— “OR.UUNMLA, Heeri-ipin; Ibikeji Olodumare; “A-je-ju-oogiin, Obiritii,-A-p’ijo-iku-da. “Oiuwa mi amoimotan, —a ko m o o tan ko se, “ A bii mi) 6 tan iba se ke. “Oiuwa mi Olowa aiyere; Omo Elesin lie-Oyin, v / “Omp prope kan t’o s’aran dpgi-dpgi. “Oiuwa mi opoki a-mu-ide-s’oju, “ Eekan ko je k’ekiin hpra, asaka-saaka akiin; “Omp Osp-ginm Tapa ti nw’ev/u ninii; “Omp Oso pa’de mpwo pa’de mese o mbeere atepaa oje. “Oiuwa mi Igbo, pmo iyan birikiti inu odd; “Omp igbii ti ns’dpe jiajia. “Ikii diidu atewp, Orp aj’epo ma pon; “Agiri Ile-Ilpgbpa, a-b’oioo\vu diwere ma ran. “Oiuwa mi A-to-iba -jaiye, Orp a-b’iku-j’igbo; “Oiuwa mi Ajild, Qgege a-gb’aiye -gun: “Odiidii ti idu ori emere; 6 tun ori ti ko suan se. “Omp ei’ejo ti nrin mirjn-mirln lori ewe, “pm.p arin ti irin Ode-Owp saka-saka.” N IN U ooki wonyi a ri isi kan ti o tp ka si ohu n Iwa Olpru n, a si ri isi m iran ti o tok a si ohun Iwa-enia: a o ko mu awon ooki ti o bo sabe isi ekini loroori.
ORI
ORI
I
I
‘ORUNMLA.’
Itumo oruko yi bi a ti gbg p lenu awpn babalawo ni pe “ Orun li o mp oola i ja /’ tabi “ Orun li n mo ilaja.” Nip a o fu kp ^ i awoiHcePeri lie wa jewp pe ija k a n ^ t a k i mbe laarin aiye ati prun, ati pe awpn ko mp eniti yio laja naa, beeni awpn ko mp pna ilaja naa. Nin u awpn ese-ifa ti o tele nihinyi a o ka ti ija yi.— 1. “ Orunm la nl ‘6 di pa aram iila;’ mo ni ‘6 di paara m iila;’ 6 ni * ‘pde aiye t’on t ’pde pru n ma pa de loni na o #’ ”—IrosuEgutan. * Nijo kan, Odg prun ran aya re wa spja aiye, awpn araiye ko mp p, nwpn ba a ja nwpn lu u; sugbpn Odp aiye ri bi a ti njp p ni iya, o saanu rp laimb p ri, o gba a silp Ipwp won. Nigbati obirin naa pada de ode prun, o robin fun pkp re iru iya ti araiye fi je on, ati bi Ode aiye ti saanu fun on. Njp pdp prun ran§p dupe Ipwp pdp aiye, o si bp e ki o masai wa pade on ni ipinna aiye on prun titi pjp mpta. Ojp p6, awpn pdp mejeeji gbe agbe emu kppkan wa sibi ade; nigbati nwpn ri ’ra-wpn, nwpn yp, pnikini si fi agbe pmu ti o gbe wa tprp fun pnikeji re bi ohun ade. Bi nwpn ti jump nmu pmu yi nwpn nsp asiri iwa aiye on prun fun ara-wpn, nwpn si nta gpdpgpdp inu ago wpn sori ilp nibikannaa. Nikehin nwpn pinnu ati-ba ara wpn da majpmu, ki oju ilp it’-pse-si yi le di ibi oritp fun ati enia ati pranko. Lati se e daju, nwpn gbe pfin jijin kan sibp gangan, nwpn si fi irawe bo o loju pe pnikpni tabi ohunkohun ti o ba dasple oju ibp ki o maa lu pfin.
ORI
I
3
2. “ Ekiti pete, adafa fun Ode aiye a bu fun Qde gru n; “ ani ki nwgn rii eiyele merin on egberin, ki igbo ti nwgn nig “ de le j;an vygh. Ode grun iiikan T’o ru, *Ode aiye ko rii .”Irosu-Eg&an. p^lupplu nwpn se ibura pe ?ni ti o ba t^te de ibe ki o maa la ohunkohun ti a ba ri ninu gfin naa Ipgbopgba lati mu idaji ki o si ku idaji silp fun enikeji. Etu jin ’fin yi a ia a, ekiri jin i a la a; nkan ko te nkan ko wp. Aja pdp prim lu pfin yi; nigbati pde aiye ba a nibp o la a meji gpge bi adehun, o fi idaji silp fun pdp prun. Inu bi pdp prun lati ri iwa pdaju yi, nitorina li o $e Ip ifi pdp eku kan bp esu lpw6 ki o le ba on gbpsan lara pdp aiye. Esu gba, esu gbp. Bi iya pdp aiye ti nja ewe plu kiri ni agbegbe ibp, esu bi i Ip jin s’pfin yi, o si yara Ip iwi fun pdp prun. Odp prun ko benibeji o la arugbo naa: bi o ti ngbe idaji tir^ Ip ni pdp aiye de, o ke; inu bi i o ni, “biotiwu ki o ri, iwp le wipe o ko mp iya mi?” Onitphun dahun o ni “biotiwu ki o ri, iwp na le wipe o ko mp aja mi?” Awpn mejeeji bprpsi ija, o si pp tobe? gbogbo araiye pejp Iptun, gbogbo ara prun pejp losi; ko si cniti o to isunmp ibi ija yi, tptuntosi nkigbe si ara-wpn wipe “p la wpn, p la wpn"” Awpn miran si nwipe “tani yio la wpn, tani yio la wpn?” Nigbayi ni Olodumare to ijade wa si aala ija naa. O si beere idi r^ O gbp tan, o ni ki awpn mejeeji Ip mu ogoogoji wa, nwpn se bpp. Olodumare wa tan awe meji oku arugbo naa le-pp o si sp p di odidi; sugbpn o fi ogoji kan sami si ibiti a ti la a; o si fa iya pdp aiye fun u pada; inu ara aiye ati ara prun dun tobpp ti gbogbo wpn da ohun pp nkigbe wipe “Orun mo won ila " Orun mo won il a"” Ayaani a mgbp orukp ORU NM ILA . Awpn p3p mejeeji si mu imp kansoso nwpn di i mu nibi eji rp, nwpn fa a ya mp ’ra wpn Ipwp Ipgbppgba nwipe “Paramila, paramila, pdp aiye on pdp prun ko ni iri ’ra m6 lai. Ayaani a nya im6 kd ’ra pni li pbi laini atunse mp. Lati pjp ajayamp ni, Qdp aiye ati pdp prun ko tun nfoju kan ’ra wpn mp kiki pe nwpn a maa kesi ara-wpn bi pkan ba spdp ja ipinna. Bi Odp prun ti ndegbp tirp Ip nijpkan, o ba pyin nla marun kududkudu pade labp pantiri o si ko o. O de ipinna o kesi pnikeji rp wipe “Odp aiye pele o, wa ko nkan ti mo fi sile de p nibi yi o; ” o wi tan o pada ’s’ ileba tire. Odp aiye ti ko ri pran pa nijp yi wa wo ipinna, o ba pyin nla meji wpnyi, o ko wpn Ip tayptayp; wara ti o si ti de ileba re, o se wpn jp. Ojump Odp prun Ip ibe awpn pyin mpta tirp wo nibiti o ko wpn Ip ipamp si, pnu ya a lati ba pgbawa owo-okun niwaju pyin kppkan: o si yara gbe owo naa kuro, o tun ilp ibp se daradara. Ojump pjp kpta mp, o tun ba owo bee nidi pyin kppkan. Nigbana ni o wa ilp si ipinna o si ke - si pnikeji re, nwpn si njp ’ra wpn bayi:— “Odp aiye, p^lp o"” “O-o-o-o-o-o-o.” “O ti se pyin rp ijpta o?” “Sise ni mo se e jp o” “ B’o I’o ti ri Ipnu rp o?” “O ma dun ladunju o "” *
Nigbana ni Odp prun dahun wipe “Haa" o tan o ku o, iwp pdp aiye ko ni ila m6 o.” $iigbpn pdp aiye yara dahun wipe “Eyi o wu ki a gbe inu ile aiye sb, Orun li o ma ni Ila o "” Ayaani a nwipe “Orun-nila. Qrunmla.
ORI I 3. “Ajo awo Ile-aiye, Abem o awo ode Isalu-pn m, awon “mejeeji ni mpade ko m gn’ipi'nna aiye on p run : a ni ki nwpn “ rubp ki obirin kansoso t ’o wa laarin v/pn ma le ba eto je mp “ wpn Ipwp. Awpn mejeeji §’eti gbonran s’ebp nwpn ko tu T a “nwpn ni kini obirin kansoso iba ti se le ba eto aiye on prim “je mp eni bi awpn Ipwp?” — Obara-meji. 4. “A-r’ ppte-sa ko s’ ojo. Oyin si ta n f ’afa de’le, eenin “ si tan f ’agan de’le; a difa fun *araiye a bii f ’ara prun nigba “nwpn ngbogun ti ’ra wpn; a ni ki kaluku wpn ni akoto kan “ oyin on akoto kan ekp fifP. Ara prun nikan I’d rub p: araiye “gbp nwpn ko ni.” — Irete-’Sa.
c/
*Obirin naa a maa j? Obi, aya Abemp awo ode isalu prun ni isc. Abemo ti Ip idebp si pran ara obirin re y i , a ni ki o ru ewurp dudu kan on egbaafa,ki o le bimp, eiyple niprin on pgberindilogun ki owo le ya wa ba wpn. Abemp ru ti ow o ko ru ti pmp . Ojp mpe Obi ko bimp, inu re baje; o si sa wa ije Ajo awo ile-aiye. Ajo da awo, ebp ijpsi ti a yan fun Abemp fun Ajo. Ajo gbp o rubp pmp, Obi si bi pkansoso fun u. Nigbati pdun yipo, ti pjp ati -lp,si ikomp pe. Obi tple Ajo Ip ipade Abemp; inu bi Abemp pipp lati ri pe Ajo te obirin on mpwp kadun li aitifi ran.sp^si on: bepni Abemp here si pro buburu isp si Ajo. Ajo si mbinu pwe pe Abemp ko tilp mu suurii gbohun kan Ipnu on ti on diyeinu mu Obi latinu ile-aiye wa ipade re. Beeni ija di nla laarin wpn. Obi takete s’okeere on nworan wpn, ko si eniti yio laja o di ajaku. Nigbati o rp awpn mejeeji ti wpn si nsimi Ipwp ni Abemp wa ikesi Ajo wipe “Ija iwere ni a ma ngbe ipinna aiye on prun ja yi o: ko si omuuja, ko si plaja; nitori ki aiye le baj? ki prun le bajp ma ni Obi se ti pdp emi Abemp Ip spdp rp. Njp , Iwp Ajo awo ile-aiye o ma wa ki a m’eti ko eti, ki a mu ohun s’apo o "” Bppni inu awpn mejeeji si tutu, nwpn si Ip iwp ikomp: nibp ni nwpn si ti peropp lati wa pa Obi tan ija aarin wpn. Nwpn se bpp nitootp, nwpn di oku Obi sinu apo kan, nwpn si fl ha s’pgbp igi kan li eba pna, nwpn ba tiwpn Ip. Nijp kpta ni Orisa nkpja Ipna ibp o ri oku Obi li egbp igi, o ji i dide o si bi i leere bi o ti se de ibe. Nigbati Obi robin fun u tan, orisa dahun pe “o dara o, ng ko le ja wpn niyan; eyiti nwpn se naa ko bum o .” Bppli o si tun di Obi sinu apo naa, o si fi ha sibiti o gbe ba a li pgbp igi, o ba tirp kpja Ip, Ayaani oo ri i, a mpa obi tan ija gbogbo ni ilp wa. *Ni saa kan, awpn araiye sigun nip ba ara prun ja; sugbpn bi nwpn ti de phin-odi prun nwpn ba ppplppp akoto pkp-flfp ti a po oyin igan mp, n vpn ko mp pe ewp mbe nisalp gbogbo akoto wpnni, nwpn fi iwpra bprpsi ekp naa imii. Lorii pjp naa ni gbogbo wpn ku patapata si phin-odi prun. bju mp mp ni jp keji, awpn ara prun jade si phin odi, nwpn ba kiki oku araiye bpprpbe: nwpn wa ina oku meje ni pasan dide ni igun mprpprin ibudo araiye.
ORI I
5. “6ke-yi-gbiri-wp ’d6 I’o difa fun araiye o bii fun ara “orun nip jump wote, nijp ti nwpn yio jija egbonlori eran edii “kanso?o ti nwpn ri-pa; a ni ki araiye ma §e melp-melp fun ara prun 6: araiye ko nwpn ko gbo, ija de.” —Ejiogbe. 6. “Hoo-hoo-m ode To difa fun Asa, a bu fun Awodi, a bii “fun Igiin s’eketa gbogbo wpn; nijp ti n_^wpn nieri pe awpn yio “gbe * ebp pmp araiye Ip de prun. Asa Ip titi o re e o ja wa’le. nwQti ni ki awpn mejeje nwpnyi maa ru oku pgbp wpn kuro li ehin odi awpn. Bayi ni awpn araiye die ti a ji-dide nwpnyi nwahala putii ni riru oku awpn pgbp wpn pade ara yi ibudo wpn ka: awpn ara prun si wa nkprin iya le wpn lori bayi pe;“ ‘Oyin Ta mu’ “Ko ma le b’ara prun ja o, ‘Oyin I’a mu.’ O gb’ogbo pip b’plp ja o, ‘Oyin I’a mu’ Ko ma le b’ara prun ja o ‘Oyin I’a mu.” Ayaani o p ri i bi araiye ti nru oku ara won kaakiri ninu aiye; oku li o nru oku. ' ^ *Ekiri kansoso naa li araiye ati ara prun wote pa 1’ o da ija silp laarin wpn; nwpn ko fe ila a meji, ara prun ni awpn ni igbe c I’odidi, araiye ni awpn ni igbe e I’odidi, ija de. Ara prun binu kp pran naa silp fun araiye nwpn si pada Ip sprun Ip imu ojo. “Kirikiri m’aiye, dugbpdugbp m’prun, ojo kakaka ko ta sile, pmp piye ko ri ’un sa-jp.” Nigbati o ppn mo araiye tan ni nwpn gbe pran ekiri naa silp, nwpn nwa pniti yio gbe e jp sode prun fun wpn: olukuluku pniti nwpn flip nsa nwpn ko fp ilp. Nikphin ni nwpn wa ilp gba aboyun kan mu, nwpn di pru pran naa rii u, nwpn ti i jade spna prun. Aboyun gbe pru re de prun aanu se Olodumare o ni “ Nitori ki iwp aboyun le ku spna prun kp li awpn araiye se ti p jadeyi? Nje, iku ko ni ipa p, arun ko ni igbe p de; raura ki o wa pada ip inu aiye o .” Olodumare pasp a gb’ agbe omi kan le aboyun lori, a ni bi o ba ti de inu aiye ki o fp p mple. Obi mu aboyun bi o ti wp inu aiye, irora si mu ki o wa ’gbe omi mpri, o gbagbe ati-fd p mplp. O wpnu ile tirp tan ki o to iranti fp p, o si bimp lojukannaa sinu agbara omi naa. Aygani oo ri i, aboyun mbi sinu aabara omi-’ra. Gbogbo aiye gbp pe aboyun de nwpn riwp wa ‘ki i w pe, — ‘O ku at’ prun bp"’ Ayaani oo gbp bi a ti nki aboyun ti o bi titun. Aboyun bi tan a nwa omi ifiwp pmp bppni ojo giiri kan o si rp ka gbogbo aiye. *Nigbati ojo yi rp titi, o pa gbogbo ina aiye run susu, pmp araiye ko tun ri ina se onjj mp; nigbanaa ni nwpn Ip wa pbp ti nwpn yio Ip fi gba ina pada ti prun v/a. j b ? yi li a ru silp tan ti a ko ri pniti yio gbe e Ip, ti asa awodi ati igun nieri ati-gbe e de ode prun fun wpn. Asa li o kp gbe e, gbogbo pmp araiye si pejp nisalp nkprin bayi fun u bi o ti ngbpbp naa Ip wipe:—
/
ORl I “gbi'rihan, Awodi lo titi o re e, o ja w a ’le gbirihan, Igiin nikan “ i’o ma gb’ebo ru de ode pru n ninu won 6!” —Osa-’Wori. Akiyesi.— Awpn ese-ifa nwpnyi ati itan won ti a ka nihin fihan dajud aju pe pka n awpn baba-nla wa nje wpn leri pe ija kan mbe laarin aiye ati pru n; ati pe ija naa here laarin enikan ti o duro fu n gbogbo aiye ati enikan ti o duro fun gbogbo prun; ati pe ija naa se lori oliun kansoso ti t’ptun-t’osi wpn ni oju si ati pe araiye ko ro ati-tum ba fun ara - prun bikose lehin ppplppp igbe; ati pe lati prun ni onilaja ti wa ati pe araiye ko ri ojurere ara-p run laisi ebp on etutu. Awpn otitp nwpnyi ni iye lori jpjp ninu ipile isin awpn baba -nla wa; nitorinaa a o mii awpn ohun akiyesi wpnni wa si egbe prp Iwe mimp Olprun fun ifiwe ki a ba le ri itoye wpn.— (a) . Ija kan mbe laarin aiye ati prun. (b) . Ija naa here larin enikan ti o duro fun gbogbo aiye ati enikan ti o duro fun gbogbo prun. Gene, iii, 17-19, 24 “O si wi fun Adamu pe, Nitoriti iwp gba ohun aya re gbp, ti iwp si je ninu eso igi naa, eyiti mo ti pase fun p pe, iwp ko gbpdp je ninu re; a li ile bu nitori re; ni ippnju ni iwp o maa je ninu re li pjp aiye re gbogbo; Egun on osusun i yio m aa hu jad e fun p, iwp yio si m aa je eweko igbe: Li oogiin oju re ni iwp o maa jeun titi iwp o fi pada si ile; nitori inu re li a ti mu p wa, erupe sa ni iwp, iv/p o si pada di
“Hohomode, Homode: (2) Asa mgbebp r’prun, Homode: O jo-jo ee mu ’jo, Ho m od e: O ra-ra ee mu ra, Homode: O f ’ehin gb’prun te o-mode, Hom ode.
(2)
Nigbati asa se e titi awodi gbe e, a nkprin naa fun awodi, bee gege nigbati igun gbe e. Igun gbe ebp de prun tan, a de ina mpnu igba ademu kan fun u wa, a si kilp fun u ki o mase fi igba naa kan ile titi yio fi de inu aiye. Igun de ori apata gbaramsa kan Ipna o ni on yio simi die, o si gbe igba naa ka ori apata; sugbpn bi idi igba naa ti kan-le, beeni ina fo-yp latinu re o si la igun lori borokoto. Ayaani oo ri i “Igun se rere o pari.”
ORI
I
erupe. Beli o le okunrin na a jad e; o si fi awon ke rubu ati ida ina de iha ila-orun ti nju kaakiri, lati maa so ona igi iye naa.” Rom . V. , 17-19. “ Nje bi nipa ese okunrin kan iku jo ba nipa enikan; melomelo li awon ti ngba opolopo ore-ofe, ati ti ebun ododo, ti nwon yio si joba ninu iye nipa enikan, Jesu Kristi. Nje bi nipa ese enikan idajo ba ba gbogbo enia si ebi; gege beeni nipa ododo enikan, ebun ofe de fun gbogbo enia ni idalare si iye. Nitori gege biotise pe nipa aigbagbo enikan, enia pipo di elese beeni nipa igbagbo enikan, a o so enia pipo di olododo.” I Kor. XV., 21-22. “ Nitori igbati o ti se pe lati ipa odo enia ni iku ti wa, nipa odo enia li ajinde ninu oku si ti wa pelu. Nitori bi gbogbo enia ti ku nipa Adamu, beeni gbogbo enia yio si di a aye nip a Kristi.” N in u awon ese-fa ti a ii oro^mimo wonyi gbelohiin, a ri pe oruko nwonyi—“ Ode aiye, Ajo; “Ode orun, Abemo;”— li a fi toka si awon eni naa ti o duro I’otun ati I’osi bi ori fun araiye ati ara-orun. Ipb ode ni ile wa ki ise kekere; fun ati-la ona titun, fun ati-te ilu titun, fun ati-da ija sile on ati-pari ija, gbogbo wa li a mo ipa ti ode ko ni ile wa. Ajo ati Abemo.— Ki ise oruko bikose ise ti a pin fun won ni mo fe ki a kiyesi nihin: *e.n. pe awon mejeji a maa pade se ikomq ni ipinna aiye on orun leekan Ipdun. Awon babalawo wipe Ajo ni Olodumarefi seojiiara-re sinu aiye nigba iwa se, O si fi gbogbo atunse aiye le e lowg; ati pe Abemo duro ni ipo kannaa li orun bi oju Olprun ati alatunse orun. Nigbati Ajo
*e.n. jasi akomona “eyini ni.’
ORI
I
ati Abemo ba pade ikomo, Ajo ni iso gbcgbo ohun ti prun fi se aiye lati esi wa; Abemo a si so gbogbo ohun ti aiye fi se pru n: awpn mejeeji a si so idi abajp fun ara-w pn, nw pn a si jiim p gbe gran aiye on pru n si etg. Ero yi je pataki kan ninu ipile isin ti nmii awpn baba-nla wa pejp Ipdppdun bi agbajp ilu fun ati-bp awpn eniti o te eya tabi orile do ti nwpn irnaa pe ni ‘egungun—isele.’ (d) Ija na se lori ohun ka nsoso ti t ’ptun -t’osin won ni ojii si. Ode aiye ati ode prun nde gfin kansoso lati pin ohun gbogbo ti o bg si i dpgbadpgba; araiye ati ara prun jump wote pa edii kansoso ti ara prun kg ati-pin fun araiye ninu re rara. Kili ohu n ti iwpnyi ndii lati fihan bikose (1) irerasile ti Olprun ti O ni ohun gbo gbo si fi mba awa enia pin ohu n gbogbo tobee ti gfe ati ofo fi je odi mejeeji asp kansoso. Eyiini ni pe ohun ti o je gfe fun wa jasi ofo fun Olprun, ohun ti o si je ofo fun wa jasi gfe fun Olprun. Ero yi je pataki k an ninu ipile isin ti nmu awpn keferi ile wa ma tpse kili o da ofo ti Ifa ba wipe on ri si wpn. Bi nwpn ba si ti gbg pe ara -p run li o da ofo ti mbpwa na, nwpn ki tun beere pe “ kili awpn fi se ara prun o?” Sugbpn lesekanna ni nwpn a maa tu mba nipa jijewp gbogbo pna ti o ba han si wpn pe awpn ti nje gfe laijuba ibiti gfe naa ti wa. Ero kann aa yi ti o li eru fun wpn jp jp li o wa nisale gbogbo suuru ati ipampra ti nwpn imaa fi gba ofo ti o ba se wpn pe “Olprun li O fe bee.” A si ri pelu niti ‘edii kans oso’ (2) irira ti O lprun Olodum are ni si abuku isin ati aabp pkan. O ya fun U lati kg gbogbo isin ati pk an naa ti d mu u wa ju lati gba wpn li abuk u ati aabp. Ese ekini ti o here ori ekini ninu Ifa jeri si planla yi ninu Olprun. Ese naa wi bayi pe.— 7.
“ Otctp ptg , Orgrp prg ; gtptp * I’a ijepa, Otptp I’a
*Oluku"uku grg nwgnyi ‘Otgtggtg’ ‘Orgrggrp’ ‘Otgtb’ ‘Tori-tori ’je ed<
ORI 1 ije imuumuu; “tori-tori I’a ifun Obamaakin n’lle IranJ6 ia 6 le baa f ’ohun tori-tori fu nni.”—fcjiogbe. (e)
Araiye ko ro ati-tiimba fun ara-oru n bikoje lehin opolopo igbe. —
Opo “ippnju ati iloyun,” Opo “egiin on o^uju,” gpo ile-ni “kuro laarin enia” ati onje enia si “ibugbe awon eranko igbe” ati si “jije koriko bi maalu,” 6po “Wkun-omi,” opo “idarii-ede,” opg “ojo sulfuri ati ina,” gpo “ida ati iyan, ati eranko bubu ru, ati ajakale arun , ” opo ikii ;—ko h a §e pe nwonyi li o kamba pmo araiye, li o te agidi pkan wpn, ti o si nmu wpn tiimba fun Olprun! Ero yi je pataki kan ninu ipile isin ti nmii awpn keferi ile wa maa tpse kili o da iku tabi arun, tabi ejo, tabi ofo ti Ifa ba wipe on ri si wpn. N itorinaa bi Ifa ri iku si wpn, nwpn a bi i
ti a nio lati tpka si ohunkohun ti o wa ni kikun, pipe, ati ailabuku. Obaiala li a pe ni Obamakin ninu ?se-ifa yi. Mu ?se-ifa naa wa si egbe pro mimp tinu Bibeli.— Lef. xxii. 20-21. “Sugbpn ohunkohun ti o ni abuku, li pnyin ko gbpdp muwa: nitoripe ki yio da fun nyin. Ati pnikeni ti o ba ru pbp alafia si Oluwa lati san pjp, tabi pbp ifp-atinuwa ni maalu tabi agutan, ki o pe ki o baa le da; ki o mase si abuku kan ninu re.” 1 Kron. xxviii. 9. “Ati iwp, Solomoni pmp mi, mp Qlprun baba rp, ki o si fi aiya pipe ati fife pkan sin i: nitori Oluwa a maa wa gbogbo aiya, o si mp gbogbo ete ironu, bi iwp ba safpri rp, iwp yio ri i; sugbpn bi iwp ba kp p silp, on yiota p nu titi lai.” Wo xxix. 17-19. “Emi mp pplu, Qlprun mi, pe iwp ndan pkan wo, iwp si ni inudidun si ododo. Bio?e ti emi, ninu ododo pkan mi li emi ti fi tinutinu se iranlpwp gbogbo nkan wpnyi; ati nisisiyi pplu ayp ni mo ti ri awpn enia rp ti o wa nihin lati fi tinutinu se iranlpwp fun p Oluwa Qlprun Abrahamu, Isaaki ati Israeli awpn baba wa, pa eyi mp lailai sinu ete ironu pkan awpn enia rp, si fi idi pkan wpn mulp si pdp rp: Si fi pkan pipe fun Solomoni pmp mi lati pa ofin rp, pri rp ati ilana rp mp.” Isa. xLii. 8 “Emi li Oluwa: eyi ni orukp mi; ogo mi li emi ki yio fifun plomiran, bppni emi ki yio fi iyin mi fun ere gbigbd.” Joh. iy. 23-24 “$ugbpn wakati naa mbp, o si de tan nisisiyi, nigbati awpn ti nsin li otitp yio maa sin Baba li pmi ati li otitp: nitoripe iru awpn pni bpp ni Baba nwa ki o maa sin on. Emi li Olprun: awpn pniti nsin i ko le se alaisin i li pmi ati li otitp.
•• ORI
10
I
lere pe “iku araiyetabj.-ti ara-« ruit?’-J3i:0 ipl si wpri/nv /on a bi i pe “ejo ara-oru n tabi ti araiye a-b’ojii perekete?” Bi ibP ba si inu ara-orun ninu 6na ibi wonyi, nwon ki itun beere pe “ kili aw on fi se ara-o ru n o?” lesekann aa ni nwon im aa itumba nipa jijewo gbogbo ona ti o ba ban si won pe awon ko sin to: nwon a si mura ati-se gbogbo etutu ati atunse ti mba mbe ni ipa won. (e)
Araiye ko le pa da ri ojurere Olo run lai-si ebo on etutu.
(f)
Lati orun ni onilaja ti wa.
Gene, viii., 20-2!. “ N oa si te pepe. fun Oluwa; o si mu ninu eranko mimp gbogbo, ati ninu eiye mimp gbogbo, o si ru ebp-pre sisun lori pepe naa. Oluwa si gbp oorun did un; Oluwa si wi li pkan re pe Emi ki yio si tun fi ile re nitori enia mo. II Sdni. kxiv., 25. “ Dafidi si te pepe k an nibe si Oluwa, o si ru ebp sisun ati ti ilaja. Oluwa si gbp ebe fun ile naa, arun naa si da kuro ni Israeli.” Heb. ix. 22. “O si fere ise ohun gbogbo nipa ofin li a fi eje wenump: ati li aita eje sile imukuro ese ko si.” N in u aw pn ese-ifa ti a fi prp mimp wpnyi gbe-lohun, a ri pe nigbati araiye nfe tumba tpkantpkan, nwpn fi eyi ban nipa fifi eran-edu kansoso naa ti nwpn ko ti fe ifisile ri spwp si prun: ewe, nwpn si fi ohun miran ti a yan li ebp fun wpn spwp si prim pelu li aijiyan. Eyi naa gaan ni aiya ebp. Bee gege li a si gbp pe Olodumare tikalare li 6 wa idiibu ija Ode aiye ati Ode prun; tabi bayi pe nigbati ko si omuiija tabi plaja laarin Ajo ati Abemp, Abemp tikalare tio ti prunwa li b si diyeinu nawp ilaja si Ajo awo inu aiye. Gb ogb o nwpn yi ndii ati-fi otitp naa ban araiye pe lati pdp Olprun ni ilaja ati onilaja ti wa iba araiye.
ORI I
11
Isa. 1:18, “Oluwa wipe, wa nisisiyi ki e si jeki a so asoy6 po: bi ese nyin ba ri bi ododo, nw on o si fun bi snoo; bi nw on ppn bi alaari, nw on o dab i irun agutan.” Isa. xiii. 15, “ Tan i eleyi ti o ti Edomu wa, ti on ti asp arepon lati Bosra wa? eyiti o li ogo ninu asp re ti o nyan ninu titobi agbara re? Emi ni eniti nsprp li ododo , ti o ni ipa lati gbala. Nitori kini asp re fi pon, ti asp re wpnni fi dabi eniti nte ohu n elo ifiinti waini? Emi tikarami ti te ohun elo ifunti waini; ati ninu awpn enia, enikan ko pelu mi; nitori emi te wpn ninu ibinu mi, mo si te wpn mple ninu irunu mi; eje wpn si ta si asp mi, mo si se gbogbo ewu mi li abaaw pn. N itori pjp esan mbe li aiya mi, pdu n aw pn eni irapada mi ti. Mo si wo, ko si o lu ra nlp wp; enu si ya mi pe ko si olugbero ; nitor ina a pa ti emitikalami mu igbala wa spdp mi; ati irunu mi, on li o gbe mi ro. On si wipe: Lootp enia mi ni nwpn, awpn pm p ti ki iseke; on si di olugbala wpn.” Eyi naa gaan li awpn keferi ile wa npe ni “ORUNMLA.’
ORI
12
“Eleri-ipln,
2
Ibikeji
Olodumare.'
Ninu iwe wa isaaju a ti se akiyesi 3d pe av/cn baba-nla wa gbagbo ps ninu planla Olcrun ti enia ko le mo titobi re yi, Olodumare ti fi Enikan se ibikeji ara-Re, On a si inaa pe Oluware si imp ninu oliun gbogbo, On a si maa li ohuu gbogbo him a, On si fi i se eleri ara-Re ninu ohun gbogbo, tobee ti ko si oliun ti Olodumare mo ti Oluware na ko mo, ko si si ohun ti Olodumare ri ti On ko ri. Eni naa ni nwon npe ni “pruunmla, Eleri ipin, Ibikeji Olodumare.” Kje, or.a wo ni Orunmla fi je Eleri ipin? Awon babalawo fi idahun si ibeere yi iatinu odiiifa wa gege bi cyiti a ko si isale nihin. (1) Orunmla je Eleri-ipin nitori On ati Olodumare li o jumo nse ikomo lode crun. P L
® “Olodumare pclu Orunmla lo ill ara-won mo ile0 / 0 ” '|‘^ o m o lorun, gbogbo orim nks idaro wipe ‘Tani yio lo isilekun naa?’ ;u gbo o siwaju "o if ’ow’o le ii?kim; beeli Qrunmla Etu dahun lati inu ile nwipe, ‘Lesi nkan ’kun Osin kakaka, lesi nkan’ kirn Osin lelele?’ O dahun o ni ‘cmi Etu ni, obeje.’ “Sugbon Orunmla dahun si i pe ‘ptu obeje, Olodumare ni ki o dehin o; o til rnp igbanaa ri? tab" o til ba won Ip s’ikomo ri? ” Eeeni Etu obeje pada sehin.
ORI
2
13
“ Edii gbo o m on yio ba won silekun; beeli Qrunrnla “ beere wipe ‘Lesi nk an ’kun Osin kaka ka, lesX nk an — “ ’kiin Osin lelele?” O dahun o ni ‘emi Edii ni, iba araa “af’ija gb’ oko; “ Sugbpn Orunm la dahun si i pe ‘Edu ibaaraa , Olodum are “ ni ki o dehin o; o ti i mo igbana ri? tabi o ti i ba won lo “s’ikom o ri?’ beeni Edu iba araa pada sehin. “Agbpnrin gbp o ni on yio ba wpn silekun; beli Orunmla “dahun wipe ‘Lesi nkan ’kim Osin kakaka ’lesi nkan ’kun “Osin lelele?’ O dahun o ni ‘emi Agbpnrin odogija onila “afifen.’ “Sugbpn Orunmla dahun si i pe ‘Agbpnrin odogija, “ Olodu mare ni ki o dehin o; o ti i nip igbanaa ri? tabi o ti i “b a wpn Ip s’ikomp ri? ’ beeni Agbpnrin odogija pad a sehin. “Ira gbp, o ni on nip ba wpn silekun; beeli Orunmla “beere wipe ‘lesi nkan ’kun Osin kakaka, lesi nkan ’kiin Osin “lelele?’ O dahiin o ni ‘emi Ira oniiwo kansoso ni.’ “Sugbpn Orunmla dahun si i pe ‘Ira oniiwo kansoso, “ Olodu mare ni ki o dehin o; o ti i mp igban aa ri? tabi o ti i ba wpn Ip si ikomp ri? beeni Ira oniwo kansoso pada sehin. “Ariwo ta lode prim pe ‘tani yio ha ba-ni silekun Osin?’ “Nigbanaa ni Edun gbp, o jade wa o ni on yio ba wpn de “ibe wo; o Ip if’pwp le ilekun, o si gbp Orunmla mbeere wipe “ ‘lesi nkan ’kun Osin kakaka, lesi nk an ’kim Osin lelele?” O “dahun o ni “Emi Edun mil ni 6!” “ Sugbpn Orunm la dahun si i pe ’Iwp Edun ol’oju “fokifoki, Iwp Edun pl’pwp ppjpppjp, dehin o; mp igbanaa, “tabi o ba wpn yun ’be ri?’ “Edun dahun o ni “ “ “
‘Oju mi meji fokifoki yi Mo fi ka ibo f ’Olpfin je; Owp mi meji ppjppp jp yi
“
Mo ii ka ibo f ’ Olpfin je ’.
ORI
14
2
‘Orunmla dahun o ni “ ‘
‘Haa! O to, Edun ol’gwo pojp, Edun elese pojo; Edu n ol’oju foki, m aa tun ror a: Itan ti o pa sile ma to 6!’
“ “ ‘
“Nigbanaa ni Edun silekun wole ikomo, 6 m’ekiin s’ekiin igbe, 6 m ’ohun s’ohun iyere, o n§e. ‘Ogijan, Edun ma mb a won to re; Ogijan, Edun mb a won lo.’ ” *
“ ‘
(2). Orun mla je Eleri-ipin nitori on ni Olodum are fi je d r i fun gbogbo awgn iriinmale ati oba, li aiye ati li oru n.—
9 “ Bi a ba dupe oore ana a gba om iran: a da a f ’Ori* '‘nlo si awujo gbogbo ininmale lo ip’obi oore.”—Ejiogbe. 10. “ Sese-ooloogoo-sese adifa f ’ Orunm la nlo ba ‘gbogbo oloja inu aiye jijakaadi.* O mii Al’A ra o da a, ‘o ko gbogbo eru re; o d’Ajero o ko gbogbo eru re: o *Ifa ti a Id nihin ie apa ikehin gsg kan ninu Ejiogbe. o si se gkan ninu awon esR ti n li erii )u[b fun babaiawoTatTH" Agbara ni m oT ilnu EabaSwo mi ki i fun mi: sibe . eru ba a tobeg ti o ii mu ini IpsTikoko kan, ti o SI mu enu sunmo eti mi nki i k^ I^ elg l ~ ~
,
\
A
*Itan yi vvi siwaju pe Olodumare ji, O mu obi oore (e.n. obi olori tabi alase) sil?: o ni on nfj eniti yio ba on pa a ninu gbogbo awpn Irunmale. Ogun de o pa a ti, o joko sibe; gbogbo irunmale de Ipkpgkan nwgn pa obi oore ti, nwgn si joko sibe nleri de gniti yio wa ipa obi ti awgn pa ti. Nikehin ni nwgn ri ti Ori yg si wgn o nyi bgwa gbirigbiri, o de o mu obi naa kan, o pa a, ariwo ta: Olodumare ni ‘Qri, jvyg ngg ii o to obi oore jp a loo tg .’ Beeni gbogbo irunmale bgresi iba Ori jowu ipo gla yi. Nwg n SI sii-mg g lati ba a ja, sugbgn ko si gniti o da Ori ninu gbogbo irunmale, Ori I’o da gbogbo wgn I’gkggkan. O da Qlgta si’le Ad o, o da Erinmi s’ode Qwg, o da PgeP?? s’ode Asin; o da Orisa s’ltapa, o da Ogun s’lle-Ire, o da Obalufgn si lyinde: o da Qrunmla s’lle-Ife. *Nigbati Ewi ti gburo isegun Oruunmla, o sa tg awgn awo Ig igbg ohun ti on le se ki Oruunmla ma le da on; a ni ki o ru owuuru eku, owuuru eja, pelu igo gti kan. Ewi gbg o o ru gbogbo nkan naa. Bi Oruunmla ti gbe ija de aafin, Ewi jade si i, o yara ko gbogbo eku ati eja wgnni ti i li aiya, o si gbe igo gti naa fun u mu. Orunmla je o mu yo tan, gti gbe e sanle: bgeli Ewi se da Orunmla, ti o si ko gbogbo gru awgn glgja-lgja li Orunmla ti da. Ayaani a nwipe ‘Ko si gba bi Ewi’. Ayaani Orunmla ni bi a ba da on, ki a si maa ko on"
ORI
2
15
“da gbogbo oloja-’loja inu a.iye o ko gbogbo eru won tan o “wa mu. ori le ile Ewi” , Ose meji. (3), Orunm la je Eleri-ipm nitori on li 6 gbe eru kiki ori nijo ti awon irunmale ndu eru oro gbe li orun. 11. “ Ewpn-ba’le-ro-worojo adifa f ’Orunm la a bii fun “gbogbo irunmale, Olodumare d’eriika’le O ranse *pe gbogbo “won ki nwon wa igbe e lo sinu aiye.”— Okanran-egiitan. Akiyesi.—Awon ese-ifa nwonyi ati itan won ti a ka nihin fihan dajudaju pe okan awon baba-nla wa nje won leri pe Enikansoso ni mbe lehin Olorun Olodumare ti 6 le mo ipin ohun gbogbo li ayie ati li orun; ati pe nipa imo yi, Enikansoso naa ni ise Ori fun ohun gbogbo.
*Ik 9 Olodumare de odo gbogbo irunmale, ko si enikan ninu won ti o ni i loliun; o de pdo Orunmla, Orunmla fun u ni itan adie kan ati opp onje. Nitori oore yi, ikp naa sofofo fun Orunmla pe ki o mase kanju gbe eru nitori “is? gbogbo mb? ninu karahun li akata Olodumare.” Es? gbogbo irunmal? pe, nwpn ndu eru gbe niwaju Olodumare, eyi ngbe eru owo, eyi ngbe eru asp; sugbpn ikp Olodumare nfi fere wi tantan fun Orunmla bayi pe:— “Oruunmla, ma sedp jok o o " ori mb? ninu aaihun.” Bayi ni Orunmla sedp joko nwo gbogbo irunmale titi nwpn fi ko gbogbo prp kpja Ip sinu aiye. Orunmla dide nigbati awpn irunmal? Ip tan, o rin Ip gaara si akata Olodumare, o si mu aaihun (karahun) naa jade ti ib? wa, o mu pna lie Aiye ppn. Orunmla ba gbogbo irunmale nwpn tidi si ati-jade si aiye, o bi v/pn eetiri, a ni omi bo gbogbo oju aiye, ko si ile nibikibi lati ti prun bp si. Nigbana ni Oruunmla tpwpbp inu karahun re yi, o mu awpn kan ti inu re jade, o si sp p le oju omi; o tun tpwpbp ib? naa, o bu ikunwp kan erup? da sori awpn naa; o tpwpbp p nigba keta o mu adi? kan oniigan marun jade, o si sp p le ori awpn naa p?lu. Adi? yi b?resi erup? die naa itan, bi o si ti ntan a, beni omi nsa s?hin ti il? si mgbaye. Oruunmla ti o da il? li o kp bp sori il?; on ko si j? ki awpn irunmal? wpnni bp sori il? titi nwpn fl ko gbogbo ?ru prp ti nwpn ru ti prun wa le e Ipwp. lyekiye ti o si to loju Orunmla ni on nfifun wpn pada; gbogbo irunmal? si tumba fun u patapata. Orunmla si nkprin bayi wipe “Aiye ma nwa Iwa r iwa o, Iwa I’ehin, Iwa"”
16
ORI
2
Aw on otitp naa niye lori jp jo ninu ipile isin ti a ba Ipwo awpn baba-nla wa (ka iwe ’Mni, ewe 16-17); nitori nwon nfihan pe awon keferi lie wa ti ni imo wiwa Jesu Kristi. A o mii awon ohun akiyesi meji naa wa s’egbe pro Iwe Mimp Olprun fun ifiwe ki a ba le ri pna ti a le maa 16 wpn lati ba awpn keferi ile wa sp aspye nipa ti Kristi.
Enikansoso ni mbe lehin Olpru n Olodumare ti o mp ipin oh un gbogbo li aiye ati 11 prun. (a )
(b )
.
.
Enikansoso naa yi ni Ori fun ohun gbogbo.
Job. x x x v i i i . 4-11. “ Nibo ni iwp wa nigbati mo fi ipile aiye sple? Wi bi iwp ba moye! Tali o fi iwpn re lele, bi iwp ba mp, tabi tali o ta okiin wiwpn sori re? Lori ibo ni a gbe kan ipile re mp, tabi tali o fi ok uta igun re le ile? Nigbati awpn irawp owurp jump kprin pp ti gbogbo awpn pmp Olprun nho iho ayp? Tabi tali o fi ilekun se omi okun mp, nigbati o ya jade bienipe o ti in u tu ja d e w a ? Nigbati mo fi awp-sanma se asp re, ati okunkun sisu se pja igbami re? Ti mo ti pase ipinnu mi fun u, ti mo si se bebe ati ilekun. Ti mo si wipe: nihinyi ni iwp yio de, ki o ma si rekpja, nihinyi si ni igberaga riru omi re yio gbe duro mp”.
Jobu ko le dahun gbogbo prp-imp wpnyi ti Olprun bi i leere ninu ori 38 de 41. M o si le sp pe ko si ninu araiye ti o ti i fpwpspiya pe on le dahu n wpn bikose Enikansoso na a ti ise Qgbpn Olprun. K a ese wpn yi:—
Owe vm. 22-30. “ Oluwa pese mi ni ipilese iwa re, saju ise re atijp. A ti yan mi lati aiyeraiye, lati ipilese tabi ki ile aiye ki o to w6. Nigbati pgbun ko si, a ti bi m i; nigbati ko si orisun ti o kiin omi pipp. Ki a to fi idi awpn oke nla sple, saaju awpn oke li a ti bi mi: Nigbati ko ti ida ile aiye, tabi petele, tabi ori erupe aiye. Nigbati o nse ipile awpn prun.
ORI
2
17
emi \va nib e: nigbati o fi osuwon ayika le oju ogbun. Nig bati o so avypsanma Igjo soke: nigbati o fi agbara fun orisun ibii. Nigbati o fi ase re fun okun, ki om i re ki o mase koja en u re; ati ofin re fun ipile aiye. Nigb ana emi wa lodo re bi onise: emi si je didun inu re lojoojumo, emi nyo nigbagbogbo niwaju re.” Tani ha li eni naa ti o fgwosoiya bayi bikose “Kristi” Eniti a pe ni “agbara Olorun ati ogbon Olorun” i Kor. i,24. Eyi na a gaa n li awo n keferi ile wa mpe ni Orunrnla. Sugbon K risti naa ti ise ogbon O lorun ni Ori fun o hu n gbogbo. Efes. i. 22. “ O si ti fi oh un gbogbo sabe ese re, o si ti fifun u lati je ori lori ohun gbogbo fun ijo enia O lor un .iv. 15. Ki a le m aa dag ba soke ninu re li ohu n gbogbo, eniti ise Ori, ani Kristi.” Ati Kristi naa yi ti ise Ori fun ohun gbogbo li Olorun fi se Eni apesin aiye ati orun:— 1 Kor. xi, 3. “ Sugbon m o fe ki enyin ki o mo pe, Kristi li ori olukuluku okonrin; ori obirin si li okore; ati ori Kristi si li Oloru n.” Filip, ii . 10-11. “ Pe li oruk o Jesu ni ki gbog bo eekun ki o m aa kunle, awo n eniti mbe li orun, ati awon eniti mbe hi ile, ati awon eniti mbe nisale ile; ati pe ki gbogbo ahon ki o maa jewo pe Jesu Kristi ni Oluwa, fun ogo Olorun Baba.” Heb. i. 6. “ Ati pelu nigbati o mu akp bi ni wa si aiye, o ni, Ki gbo gbo angeli Olo run ki o si m aa foribale fun u” Or. Daf. x c v i i . 7. “Oju yio ti gbogbo awon ti nsin ere fifin eniti nfi ere se ileri ara won: e maa sin i, gbogbo enyin olorun.” On a wo ni Orunrnla fi je Ibikeji Olo dumare? Awo n babalawo fi idahun si ibeere yi latinu odu-ifa gege bi eyiti a kp si isale nihin: (1).
Orunrnla je Ibikeji Olod um are nitori On ati Olod umare li o jump here iwa nigbati nwpn ko tile ti i ni ohunkohun miran ju ohun - Iwa - Olorun.
ORI
18
2
12. “Ojii mpon Olodumare, ojii mpon Orunmla: “Olodumare ni ki Orunmla rubo; Orunmla ni ki Olodumare “ naa rubo ke. Nw on jum p yan asobilikl eranla kook an “ ati ogbopgbokanla li ebp fun ara-wp n. Awpn mejeeji gbp ebp nwpn rubp.”—Ejiogbe.**
(2).
Orunm la je Ibikeji Olodum are nitori lehin Olodu mare, On nikansoso li o kii ti o tiin kapa Esu.—
13. “ Eni buru ku nsalp kuro loju Olodumare, Olodu mare “ ke- le e wipe ‘E mii u !’ Eni bu ruk u tese mp ’rin nip, “beeli a ko ri enit’ o le mu u sile ninu gbogbo ininmale t’o “pejp s’iwa prun.
“ Eni buruk u la won kpja pa tapa ta tan 6 wa kan Orunmla, Orunm la m u u sikun o fa a pad a Ip fun Olodumare, O lodu “mare gbe e s’eewpn. “ Ayaani oo ri i Olodum are wipe ki Orunm la jok o ti On: “O ni ‘Iwp Orunmla nikansoso ni ki o maa ri mi fin ninu “ gbogbo inin ma le.’ ”—Ejiogbe. Akiyesi.—Awpn ese-ifa nwpnyi ati itan won ti a ka nihin fihan pe wiwa-siwaju-ohun-gbogbo je ero pataki kan ti nwpn ni si Olprun: ati pe wiwa ohunkohun miran lehin
*F,yi tii pp a ti a kin i ese ti o li eru julp fun babalawo lati ki.
'*11
iwe yi:
Itan abami yi wi siwaju pe nigbati Olodumare ati Orunmla rubo yi tan, bi nwpn ti jump nrin Ip, nwpn jin sinu pfln nla kan; nwpn si wa ninu ppplppp ebi nibe fun pjp pipp tobpe ti nwpn ko fi le jade mp. Ni alabapade ni Edun wa iba wpn ninu ippnju nla yi, o ni “Haa"” o yara nip iwa eso igi gbogbo ka wa ifun wpn je nibe titi oju wpn fi wale, ti imi fi ko wpn die lati goke. Nigbati nwpn goke tan, sibpsibe nitoriti ara wpn koi tii padabp sipo tan, nwpn Ip iti ara-wpn mp odi ti a mpe ni Odi Ikomp li ode prun. lyoku itan yi li a ti sp saaju ninu pse ’kejp ti iwe yi. Asiri nla yi ti Edun nikan mp li o fi ni igboiya lati silpkun wple ikomp Orunmla ati Olodumare Iptp (wo pse ’kejp).
ORI
2
19
OloruQ na Olgrun li ebo kan; ati pe nl riru ebo ula yi, ogboogba ni inawo re fun (31odumare ati Orun m la: ati pe ko si enikan ti o kapa Esu bikose Eniti o ba Olorun dogba. Awon otito nwonyi niye lori jojo ninu ipile isin ti a ba Ipwo awon baba-nla wa: e.n. pe nwon ya Olorun Olodumare tikalare ati ohun-iw a Re kuro lara o hunkohun ti ise ohu n-e loipile-eda, nwon si ya Orunmla ati ohun -iwa re baka nna kuro lara ohunkohun ti ise ohun-elo-ipile-eda. Bi a ba mu awon ohun akiyesi wpnyi wa si egbe prp Iwe Mimp Olprun fun ifiwe, a oo ri pna ti a le maa 16 wpn lati ba awpn keferi ile wa sp aspye nipa ti Kristi. (a). Wiwa Olpru n siwaju ohu n gbogbo je ero pataki kan ti o ye ki a ni si Eniti a pe ni Olodum are. Or. Daf. 90. 2. “Ki a to bi awp n oke nla, ati ki iwp ki o to da ile on aiye, ani lati aiyeraiye, iwp li Olprun. Job. x x x \ i . 26. “ Kiyesi i, Olpru n tobi, awa ko si mp bi o ti tobi to! beeni a ko le iwadi iye pdun re ri.” Rom. x i . 36. ohun gbogbo.”
“N itori lati pdp re, nipa re, ati fun u li
Heb. Hi. 4. “ Lati pwp enia kan li a sa ti kp olukuluk u ile; sugbpn eniti o kp ohun gbogbo ni Olprun.” Ifi. /. 8. “ Emi ni Alfa ati Omega, ipilese ati opin, eniti o mbe, ti o ti wa, ti o si mbpwa, Olodumare. i v . 11 Oluwa, iwp li o ye lati gba ogo ati pla ati ag bara: nitoripe iwp li o da ohun gbogbo, ati nitori wiwu re ni nwpn fi wa ti a si se da won. Ero wiwa Olprun siwaju ohun g bogbo U o mu awpn baba-nla wa kan ak oko kan ti oju mppn Olodum are ti o si m ppn Ibikeji R e pelu; e.n. pe akok o kan ti Olodum are ati Ibikeji Re ti wa li aitii da edak eda kan , ani nigbati a koi tii da nkan naa tikalare ti ise ohun-elo-ipile-eda.
20
ORI
2
Niti OIoTun, gbogbo eda li o ti ban fu n Oloru n lati gbogbo aiyeraiye bienipe a ti da won; sugbon niti awa enia, a ko le ri tab i ki a ni oh un ti koi tii si. Oh un ijinle nlanla si ni ero yi li okan awon babalawo ti o ba gbo ’fa de ibe ni ile wa; nitori nigbati a tiin fi ibeere yi fun won pe “Tali eniti o kg w a p ato ninu Olodumare ati Oru nm la?” nwon dahu n pe “Ko si eniti o mo eniti o kp wa ninu won nitori ‘Li ojp ti a ti mu oko li a ti mii agbe.’ ”* Eniti o ba ro idahun kekere yi wo yio ri ijinle ero ti awpn baba-nla wa fifun ohun-iwa Olodum are ati Ibikeji Re. (b). Wiwa oh un -ko hu n miran lehin Olorun na Olodumare li ebp kan. (d). Ni riru ebp nla yi, pgbppgba ni inawo re fun Olodumare ati Ibikeji Re. Isin otitp, e.n. oju ibp ati pna mgba-bp ti o se itewpgba Ipdp Olprun Olodumare je ilana a-t’pwp Ontikalare wa: ati bi ko ti si isin kan ti o pe-ye lain! ebp ati irubp, o daju pe araiye ko le tikarawpn ronu kan ebp ati irubp laisi ifihan a t’pwp Olp run wa. Nigb ati a ba si ro o pe bikose Olprun Olodumare ba tewpgba ebp ti mbe ninu isin kan, isin naa ko le igbe oliisin, yio wa idaniloju pc ebp ni kdko ati emi isin. Ki ha li ebp? Ebp ni nina ara-eni tabi ohu n ti o dipo ara-em fun “ati-mu anfaani ba ara-eni tabi elomiran; eyi ni owurp ebp. Ero yi gaan ni awpn keferi ile wa nl sipa ebp nigbati nwpn nwipe ‘Olodum are rub p’ tabi ‘Orun mla ru bp ’ e.n. pe nwpn na ara wpn jade ki nwpn ba le ni ohun gbogbo wpnyi ti a ri ati ti a ko ri. Pataki kan li o si je ninu igbagbp wpn pe ohun
*Ki akawe yi ro o jinle:— “Ewo li o ko wa? ile oko ti a san, tabi eba oko naa?” Iwo yio si ri pe l?sekannaa ti a ti beresi sisan oko, leseicannaa ni agbe re iti ihan p?lu r6.
ORl
2
21
gbogbo ti a ri ati ti a ko ri (e.n. gbogbo eda), ni ati ibere ati aarin ati opin wiwa won latinii ati nipase ebo ti Olodumare ati Orunmla rii li owuro iwa. Nje eyi mu ki a ri ip5 nlanla ti nwon fifun Orunmla niti pe ki o je enikansoso naa ti t’on t’Olodumare jumo rubo gbogbo eda. (e) Ko si enikan ti o kapa Esu bikose Eniti p ba Olod umare dpgba ninu ohun gbogbo. Lotitp ni awon enia ile wa npe Esu ni Elegbara, sibe nwon njewo ninu isin won pe Olodum are ati Ibikeji Re lag bara ju Esu lo fiiri. Nigbati a si bi won leere pe “Eetise ti e fi mbo Esu to bayi nigbati e mp p li eni buru ku?” idaliun ti aw on babalawo fifun ibeere yi ni wonyi pe,— “Olprun li o da Esu, ti O si fi i je oye alagbara spdp araRe Iphun. Nigbati Olprun si mp pe Esu ko tiin san mp. On ka nn aa li o le e wa sinu aiye. Ag bara Olprun tobi ju ti E§u Ip fiiri, sugbpn bee gege ni agbara Esu si tobi jii ti awa pmp araiye Ip. Ida ti Olprun ti da Esu lati phiin wa ni ko se ipa-d a Ipwp awa pmp araiye li o je ki a kiiku maa be e ki o ma baa fi buburu re se wa. Enyin ko gbp bi owe wa kan ti wi pe ‘Bi ko rpp-nii 1’ apa baba, a rpp-nii I’apa iya’? Qrun Ipphun ko san Esu, sisan li aiye wa isan jii prun Ip ni.”
Ero yi m'ye lori jpjp niwpnbi o ti tpka si pna pataki ti a ba maa lo iyanju wa si laarin awpn keferi ile wa lati mu wpn mp daju pe Olprun ko le Esu bp si aiye lati maa pa araiye li aiya niican, sugbpn O si ti ran Enikan ti o le kapa E?u wa sinu aiye pelu lati je Ogagun igbala araiye: ani Eni naa Jesu Kristi Olugbala. Luk. xi 21-22. “N igbati pkpnrin alagbara ti o ham pra ba nsp aafin re, erii re a wa li alaafia: Sugbpn nigbati pkpnrin alagb ara jii u ba kplu u, ti o si segun re, o gba gbogbo iham pra re ti o gbekele Ipwp re, a si pin ikogun re.”
22
ORI
2
i Tessa, v. 8-10. “ §ugbo n e jeki awa ti ise ti osan, ki a ma wa li airekoja, ki a m aa gbe awo-aiya igbagbo ati ti ife wo; ati fun asibori irin, ireti igbala. Nitorip e Olorun ko yan wa fun ibinu, bikose lati ni igbala nipa Jesu Kristi Oluwa wa. Eniti o ku fun wa, pe bi awa ji tabi bi awa siin, ki a le jum o wa laaye pelu re .” Heb. II. 14-15. “Nje niwon bi awon omo ti se alabapin ara on eje, on tikarare pelu si mu ipa ninu re naa; pe nipa iku ki o le pa eniti o ni agba ra iku run, eyini ni Esu; O si yo awon, nipa iberu iku, ti mbe labe ide li ojo aiye won gbogbo.” i John. ii. 8. “Enikeni ti o ba dese ti Esu ni; nitoriti Esu ti se lati igba atetekose. Nitori idi eyi li Qmo Olorun fara han ki o le pa ise ti Esu run.”