EB BÓ DE ESTERA OJUANI SHOBE
“OJUANI SHE SHOBBE ACHÉ MÍ ,ACHÉ ADIE ,ACHÉ ODDANI OMO OFO UNTORI. “OJUANI SHOBI TABAKOYU BAIN-BAIN IKU BAIN-BAIN LOBATIADIFAFUN O UN AWO MEDILOGUN TINLODIFA ILE OLOFIN”
Con las palmas hacia arriba sobre la estera ,moviendo los dedos sobre la estera se canta: “OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE”
Coro:OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE “OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE” Coro:OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE “OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE” Coro:OJUANI SHOGBE LERÍ ECHU BAWAO ESHU AWA TETETE EYIOKO
“EYIOKO KINI OMO FAKO,NKA BURUKÚ EGGÚN, ONA TEMI TAN TEMI TAN TEMI LE SIKO TO LERÍ KO LE MIMÓ ,UMBA LEKO”
OYEKU MEJI, OYEKU MEJI, OYEKU MEJI LEEMETA.MO BE YIN, BI IKU BA SUNMO ITOSI KI E BAMI YE OJO IKU FUN.SI EHIN OGUN TABI OGORUN ODUN, O DUN, TABI BI IKU BA NBO KIE BAMI YEE SI EHIN OGOFA.ODUN TIATIBI MI SINU AYE KI E BAMI YE OJO IKU FUN ARA AR A MI ATI AWON OMO MI TI MO BI.KIAMAKU NI KEKERE, KIAMAKU IKU INA, KIAMAKU IKU ORO, KIAMAKU IKU EJO, KIAMAKU SINU OMI. ÌYÒYÒ KE WA YO FUN (IRE) MI O. ÌYÒYÒ KE WA YO FUN (IRE) MI O.A MI YÒ NILÉ, A MI YO LÁJÒ. ÌYÒYÒ AYÈ E, ÌYÒYÒ. “EYIOKO TEMITA,TEMITA INCHÉ TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN” “EYIOKO TEMITA,TEMITA INCHÉ TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN” “EYIOKO TEMITA,TEMITA INCHÉ TEMINNOLOKUN MOYUBA ASHE, MOYUGBA OLOKUN” OGUNDA
“OGGUNDA ITÁ OFERAYESUN, EBANSUN ELEMÍ” “OGUNDA AFARAYE, AFESUYE LESILOSUN
OGUNDA MEJI, OGUNDA MEJI, OGUNDA MEJI, MO BE YIN, KIEDAI NI‟DE ARUN ILU EJO, EGBESE ATI BEEBEE, KI E D A‟RI IRE OWO,ISE ORO OMO OLA EMIGIGUN, ARALILE ATI BEEBEE S ODO MI,KI E DA MI NI ABIYAMO TIYOO BIMO RERE TI WON, YOO GB‟EHIN S I – SINU SINU AYE ATI BEEBEE. OGUNDA MEJI. “AKERE KONKOGBOGBO ONICHÉOLODDO. ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ LO KI LEYOO” Coro: ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ KI LEYOO” ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ LO KI LEYOO” Coro: ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ KI LEYOO”
ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ LO KE IBBO” Coro: ATARUMÁ ATARUWÓ ,KOSÍ LEYÓ LO KE IBBO”
ATARUMÁ ATARUWÓ, KOSÍ LEYÓ LO KE IBBO” Coro: ATARUMÁ ATARUWÓ, KOSÍ LEYÓ LO KE IBBO” OFUN-MAFUN
“OFUN MAFUN YEYEDE ,OFUN SERO ,OFUN SARÓOFUN FUN IKÚ ,OFUN FUN ARO ,OFUN FUN INHA ,NKOLÉ ECHU”
OFUN MEJI OLOWO, OFUN MEJI OLOWO, OFUN MEJI OLOWO, MO BE YIN, KI E FUN MI L OWO ATI OHUN RERE GBOGBO.EYIN LI E NFUN ALARA LOWO KI E FUN EMI, NAA L OWO ATI OHUN RERE GBOGBO.EYIN LI E NFUN AJERO L OWO, KI E FUN EMI NAA L OWO ATI OHUN RERE GBOGBO.EYIN LE E NFUN ORANGUN ILE – ILA L‟OWO, KI E MASAI FUN EMI NAA L‟OWO ATI OHUN R EREGBOGBO ATI BEEBEE TITI LO. OFUN MEJI OLOWO. OFUN MAFUN KIMAFUN OFO, KIMAFUN ARUN, KIMAFUN ELLO, KIMAFUN GBOGBO ARAYE KALEPA NIKU. OFUN MAFUN ARO MAFUN, MAFUN OFUN BREKETE OFUN SOLOYU, WA MI KO MIO “OJORU JU-JU WA MI K OMÍO” “OJORU JU-JU WA MI K OMÍO” Coro:“OJORU JU-JU WA MI KOMÍO, OJORU JU-JU
EPA WA MI KOMIO. Coro:“OJORU JU-JU WA MI KOMÍO, OJORU JU-JU WA MI KOMIO IROSO
“IROSSO IYALOCHA ITÁ KIN KI ENÚ ABBÓ OFO,INHA ,IKÚ IYÁ OPO OMO LERÍOMO OLORUN ILÉ IYA ACHÉ LENÚ”
IROSUN MEJI, IROSUN MEJI, IROSUN MEJI, MO BE YIN, KI E JEKI AWON OMO – ARAYE GBURO, MI PE M O L‟OWO LOWO. PE MONIYI, PE MO N „OLA, PE MO BIMO RER E ATI BEEBEE.KI E JEKI WON GBO IRO MI KAAKIRI AGBAYE, IROSUN MEJI. EMI WON, EMI WON È L E PA „ÀPÉNI. ÌDÁRÍ O RÓ KI PA ORÓ.EMI WON, EMI WON È LE PA „ÀPÉNI. AKUA MASHA, MASHA DIRE, KAFI KAPALENO AMBEBE KIN INAFUKUOSO, IROSO APATARITA ABEBEKIN INAFUKUOSO KIN APANDEURE APALASHENU. “ABO NIRE KACHAR Á ABONIRÉ, ABO NIRE
Coro: ABO NIRE KACHARÁ ABONIRÉ, ABO NIRE “ABO NIRE KACHAR Á ABONIRÉ, ABO NIRE Coro: ABO NIRE KACHARÁ ABONIRÉ, ABO NIRE “ABO NIRE KACHAR Á ABONIRÉ, ABO NIRE Coro: ABO NIRE KACHARÁ ABONIRÉ, ABO NIRE EYEUNLE
“EYEUNLÉ TEMI OMO SUNKUN, DEDE LA BOLU, DEDE LA BOSI,DEDE LABALOSA , TOTO, TOTO BA FIRENU, ODARA AKO, ALU BASHE ATI KO LERÍ TO IBAN ARO, ARO TONU ALA BI SENÚ” EJIOGBE, EJIOGBE, EJIOGBE. MO BE YIN, KIEGBE MI KI‟MI NIYI, KI E EGBE MI, KI‟MI N‟OLA, IFAKIFA KIINI‟YI KOJ A EJIOGBE.EJIOGBE NI BABA – GBOGBO WON.KI GBOGBO ENIYAN KAAKIRI AGBAYE GBARAJO, KIWO N MAA GBE „ MI N‟IJA, KIEGBEMI LEKE OTA. KI NLE „KE ODI. KIEMAA GBE‟MI N‟IJA KIEMAA GBE MI LEKE ISORO LOJO GBOGBO NI GBOGBO OJOAYE MI.
KIEMAA GBE IRE KO MI NIGBABOGBO TABI KIEMAAGBE FUN MI(O FUN NI IYAWO ) AYÉ SÈRÉN TI DUN, O DUN JU OYIN L O. AYÉ SÈRÉN TI DUN, O DUN JU OYIN L O.
ÒRÌSÀ JÈ AYÉ MI O DUN, ALÁYUN GBÁLÁYUN. ÒRÌSÀ JÈ AYÉ MI O DUN, ALÁYUNGBÁLÁYUN. BI A BA BO OJU, BIA A BA BO IMU, ISALE AGBON NI A PARI RE.A DA FUN ORUNMILA NIGBATI O NLO GBA ASE LOWO OLODUMARE.O RUBO OLODUMARE SI WA FI ASE FUN U.NIGBATI GBOGBO AIYE GBO P O TI GBO ASE L OWO OLODUMARE NWON SI NWO T O O.GBOGBO EYITI O WI SI NSE. LATI IGBANA WA NI A NWIPE “A LA MOIYÉ ,ALA MOIYÉ Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO” “A LA MOIYÉ ,ALA MOIYÉ Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO” “A LA MOIYÉ ,ALA MOIYÉ Coro:ONA ENU KUA KUA IBBO” OBARA
“OBBARA ENIBARA ,EYEGBARA ,ELEGBARA KIKATE OMO KETELAROFUN ECHÚ JONJORO YEYERO JONJORO,YOBI-YOBI LABBÉOBI OMA ILÉ TO DEKOLE BAMÍ”“OBARA MEYI ONIBARA
OLABARA EYEBARA KIKATE AWO KOMAKATO ARAYE KOMAKATE ARA ORUN ADAFUN BOGBE EYEOKO OROFO LORUBO BOGBO TENUYEN KOKORO” “OBARA MEJI, OBARA MEJI, OBARA MEJI, MO BE YIN, KI E SI‟NA AJE FUN ME, KI AWON OMO ARAYE WA MAA BAMI, RA OJA TI MO BA NIITA WARAWARA, IPEKU ORUN E PEHINDA L ODO MI. IBARA MEJI DE AT BEEBEE” OBARA, ONI BARA, KIKATE IKU, KIKATE ARUN, KIKATE OFO, KIKATE ARAYE, TINSHE OMO OKUNI, KUALUJERO OYANSO. AWÚN DE WA. AWÚN DÈR Ò. ORÍ IRE L‟AWUN NW E.ODÁN NBI, ODÁN NRE. ODÁN TI ESELE IBÙDÓ O. ODÁN TI ESELE IBÙDÓ O. “OBBARA JI DUN DUNOBBARA JI DUN DUN.
Coro.......UM “OBBARA JI DUN DUNOBBARA JI DUN DUN. Coro.......UM OBBARA JI PIKUA; OBBARA JI PICUA. coro........UM OBBARA JI PIKUA; OBBARA JI PICUA. coro........UM TANI ONA OMÍ FAO”
OSA
“OSÁ GBOGBO ERIBO,ENIGBO ONATEMÍ IKÚ ,ARO ,OFÓINBAMTIN ILÉ IYO IYÁ ONILÚ”
OSA NIKO, IWORIWO AWO, TANI FOKUN, AWO OWO SI KONKON OFADARA OSHORO. OSA MEJI, OSA MEJI, OSA MEJI, MO BE YIN, KI E JEKI NDI ARISA-INA, AKOTAGIRI EJO FUN AWON OTA, KIESO MI DI PUPO GUN RERE, KI‟MI R‟OWO SA N OWO ORI, KIMI R‟OWO SAN AWIN ORUN MI ATI BEEBEE. OSA MEJI. “FUFULEKE FEFE IKU, OSÁ MODA, MODA AFEFE IKU
Coro: ..........UM. “OSÁ MODA, MODA AFEFE IKU Coro: ..........UM “OSÁ MODA, MODA IYANZA IKU Coro: ..........UM. “OSÁ MODA, MODA IYANZA IKU Coro: ..........UM
ABO FIROLO, FIROLOBALE, ABO FIROLO, FIROLO BALE Coro: ABO FIROLO, FIROLOBALE ABO FIROLO FIROLO BALE Coro: ABO FIROLO, FIROLOBALE ABO FIROLO FIROLO BALE ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE, MURELE GUALE Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE. MURELE GUALE Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE. MURELE GUALE. ABO FIROLO, FIROLOBALE, ABO FIROLO, FIROLO BALE Coro: ABO FIROLO, FIROLOBALE ABO FIROLO FIROLO BALE Coro: ABO FIROLO, FIROLOBALE ABO FIROLO FIROLO BALE. Coro: ABO FIROLO, FIROLOBALE ABO FIROLO FIROLO BALE ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE, MURELE GUALE Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE. MURELE GUALE Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE. MURELE GUALE Coro: ABO MURELE, MURELE GUALE,ABO MURELE. MURELE GUALE.
ODDI
“ODDÍ OCHA LOMAKO ,ELERIBBÓ OCHA OMO IYÁ ARÓ OMOBÁ IKÚ,IKÚ KODIMA ,EYO KODIMA
,OFO KODIMA. ODI, ASHAMA ARUMA, MAMA DINA KOYO DINA, ODI GAGA, ODI GOGO OKURUJELE, ADIFAFUN OBATALA” ODI MEJI, ODI MEJI, ODI MEJI, MO BE YIN, KI E BAMI DI ONA OFO, KI E BAMI DI ODO OFO, KI E B AMI DI ONA EJO, KIE BAMI DI ONA IBI, KI E BAMI DI ONA ESH U,NI NRI‟DI JOKO PE NILE AYE. KIEMA JEKI NBA WON KU – IKU AJOKU.OKAN EWON KIIKE.KI E SE – ODI AGBARA YI MI KA, KI OWO MI KA‟PA OMO ARAYE BI OMO ODI TIIKA‟LU.
Se canta: “TANI OBA LOWO MI ADDÁLOWO MÍ, ADDÁ LORISSÁ Coro: ADDÁ LOWO MÍ , ADDÁ LORISSÁ” ADDÁ LOWO MÍ, ADDÁ LORISSÁ Coro: ADDÁ LOWO MÍ , ADDÁ LORISSÁ” ADDÁ LOWO MÍ, ADDÁ LORISSÁ Coro: ADDÁ LOWO MÍ , ADDÁ LORISSÁ” ADDÁ LOWO MÍ, ADDÁ LORISSÁ
Coro: ADDÁ LOWO MÍ , ADDÁ LORISSÁ” OSHE
“OSHE MULUKU, MULUKU SARA UNDE LEPELEPE, OCHÉ PELÉ PELÉ , OCHE KALEENI TULESHE
,OKO MALEKÚ ,MALEKÚ ENÚ KODA, IGBA ACHÉ ,LEGBA KOIDÉ FUN MI. IBA DE YEWA IYAKOIDE. OSHE KULUKUSHE MULUKUSHE AWO, KULUKUSHE OMO. OSE MEJI, OSE MEJI, OSE MEJI, MO BE YIN, KI E FUN MI NI AGBARA,KI NSEGUN AWON OTA MI LONI ATI NI GBOGBO OJO AYE MI, KIEMAA BAMI FI ISE SEGBOGBO AWON ENITI NWA IFARAPA ATI BEEBEE FUN MI.KI E JEKI NGBO KI NTO KI NPA AWU SEHIN. OSE MEJI. “IFA DE YEWA FOUNDÉ; IFA DE YEWAOO I YAKOIDÉ Coro: GBOGBO YEWA Ó,IFADE YEWAOO IYAKOIDÉ” “IFA DE YEWA FOUNDÉ; IFA DE YEWA I YAKOIDÉ Coro: GBOGBO YEWA Ó, IFADE YEWA OO IYAKOIDÉ” EYILA SHEVORA
“EYILA SHEBORA AGANAGAYA, AGATIAFAYA INIRU KOCHETI IKÚ ,KOCHE TI ARO KI OMI TUTO TOKUN AINA”EYILA SHEVORA KAWO KABIESILE OLUEKO ASI OSAIN INA RULU
BARA LU OLU KOSO BAMBIOYO. Mientras se canta se aplaude: “E NI LU MAYO Coro: Ee MAYO. “E NI LU MAYO Coro: Ee MAYO. “E NI LU MAYO Coro: Ee MAYO. “E NI LU MALU
Coro: Ee MALU. “E NI LU MALU Coro: Ee MALU. “E NI LU MALU Coro: Ee MALU. Mientras se canta se llevan las manos a la estera y luego a la boca: “TANI ALADDO LEWAMÍ. A LA DO BEGUANO Coro: MOYE E MOFIYÉ, ENÍ ALADDO MOFIYÉ” “TANI ALADDO LEWAMÍ. A LA DO BEGUANO Coro: MOYE E MOFIYÉ, ENÍ ALADDO MOFIYÉ” “TANI ALADDO LEWAMÍ. A LA DO BEGUANO Coro: MOYE E MOFIYÉ, ENÍ ALADDO MOFIYÉ” Mientras se canta se golpea el pecho con la mano izquierda: “GUARUOO AKUNAMBÓ ABÓAKUNAMBÓ “GUARUOO AKUNAMBÓ ABÓAKUNAMBÓ “GUARUOO AKUNAMBÓ ABÓAKUNAMBÓ
----ALAFIN LEKEDDA” Se cambia de posisión y con la mano derecha en el caracol se canta: “LARILA FICHETE IBARAOTA. “LARILA FICHETE IBARAOTA FICHETE IKU, FICHETE ARUN, FICHETE ELLO, FICHETE EGBA, FICHETE FITIBO, FICHETE AIINI EPO. ORICHA FIFETO.....ARA GOGO” 2 o 3 bis. Se cambia nuevamente para la izquierda y se dice: “ASÍ COMO CAMBIO DE MANO Y DE POSISIÓN CAMBIO OSOGBO PARA IRÉ Y LO QUE LA MANO DERECHA HIZO L IZQUIERDA NO LO PUEDA DESTRUIR ” SE PROCEDE A PREGUNTAR QUE SE VA Y QUE SE QUEDA. DESPUÉS SE PREGUNTA SI CIERRA EL EBBO Y SI ARUFI, ARUFI, ARUDDA, ARUDDA. LUEGO SE PROCEDE A CERRAR EL EBBO CON EL EFUN Y OWO El Iyabo levanta el ebbó y lo deja caer encima del caracol (repite este acto tres veces) se recoje y se reza: OKANA SA MOKESA BILARI AWA TETETE MOKESA BILARI IKU ARUN EYO OFO EGBA FITIBO INYA…..
Luego se pasa por encima de la cabeza 3 veces por encima de la cabeza de iyawo diciendo: “OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE”. “OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE”. “OKANA-SA BILARI ESHU BAWA TETETETE” . El Iyabo toma el ebbó ,acompañado por la Oyugbona y lo deja el pie de Eleggúa. cuando va a dejar el ebbó se canta: ODI FUMBO KARIDEFUN KARAWE DENDEFUN KARKO ELEGUA ESHU BAIKU NIWE INLE MOWANILE ELEGUA ESHU ODARA OFUNDI ADIFAFUN ETBA AUN BATON LONI OBINI LELE EBEYI AWO, ADIFAFUN AYE EYELE LEBO IDIFUN ADIFAFUN ESHU ANIRE LAWO OTAYEIBE ADIE KOYOKO EYELE, BABALAYIKI AWO TENIYI AWO ELEGUARA SOKUN SOKUN LAYE OBUNDI OFOJUDE ABURE ALODE EBBO ,OBALU OGUN ODARABI AWO TENIYI OMO ELEGUARA ODI FUMBO. “ECHÚ O ,ELEGBARA É, ECHU O ELEGBARA É, ELEGBARA MOFORIBALE ,ELEGBARA AGÓ” Cuando vuelve se agacha a besar la estera y el oriate le sopla efún por arriba de la cabeza.
Esta igbaasheorishasconsistia en un guiro forrado con cuentas multicolores y consagrada con los siguientes atributos:
1)Guacalote verde -representa el nacimiento(ibi). 2)Huesito de la pata del chivo representa a la muerte (iku) 3)El coral representa a sodorisha (jokosha) 4)El mate representa a osanyin
5)El ikin representa a orunmila 6)leriagboran (cabeza de muneca) representa los osobu 7)semilla de zapote representa a la enfermedad (arun) 8)Oro y plata representan los planetas 9)gbogboashe representa el ashe de olodumare 10)ilekegbogboorishas (cuentas de los orishas) a los orishas 11)Igba (el guirito) representa el sacrificio (ebo).